Dishing Out Yoruba The Best Way (warning: do not translate with software to avoid misinterpretation)

Ijapa Tiroko Oko Yannibo (Olagoke Ojo)

No comments :
Gbogbo itan tio wa ninu iwe naa lo da lori Ijapa. Gbogbo ogbon ewe to fi n yo ara ninu ijangbon ni onkowe se afiyan re ninu iwe yii.
Ogun ni gbogbo itan inu iwe naa, otookan won lo si ni ona – oro ati koko.
·     Aso ti o suyo ninu itan :-
1.     Igbeyawo
2.     Isinku
3.     Ikomojade
4.     Oba jije
·     Ogbon isotan :- Ogbon isotan alo ni Olagoke Ojo fig be itan re kale. Nitoripe Ijapa eranko ni o n ba eniyan, Iwin ati eda yoo ku se po ninu iwe naa. O lo ojumilose pelu ninu gbogbo itan re.
·     Eda itan:- Olu eda itan ni Ijapa, ko si inu itan ti ko ti kopa. Awon eda itan miran ni oba Ilu, Iwin, Oni, Atioro, Igbin, Eniyan, Adigbonnaku, Etan.
·     Ibudo itan :- Inu igbo, aarin ilu, inu odo, ori igi
·     Ilo ede :- Orin, Ifiromorisi, ofo Afiwe taara, Owe.
(ITAN 1: Ijapa ati Atioro)
Ogbon ju agbara lo ni koko oro nitori ogbon ni Ijapa fi n yo ara re ninu ewu. Ijapa mu, Atioro n jerin ofe, Ijapa fe mo asiri. Ijapa so fun un won jo lo si oko yii. Atioro setan Ijapa ko setan, Atioro tii.
(Itan 2: Ode, Ara – orun ati Ijapa)
Iponju lomu ode yii bo sinu igbo. Eye orofo to pa to si salo je ki o bo si arin awon ara – orin nibi ipade. Koko ibe nipe iya kodara lara. O to, o ro fun won, won si fun un ni ise emu dida fun ponun marun – un lojoojumo. Koko miran ni pe, ma finu han eni kan. Ara re ko ya, o be Ijapa o si so eewo ara – orun fun un. Ijapa dajaa, wahala de.
(Itan 3:- Ijapa ati Omobinrin Oba)
Alagbara loba fe fomo fun. Ninu idije oko riro to waye, Kannakanna ni ko ba fe omo oba sugbon Ijapa pofo le Omobinrin lori. Iyen tele e, Oba ko sir anti omo re mo.

No comments :

Post a Comment