Dishing Out Yoruba The Best Way (warning: do not translate with software to avoid misinterpretation)

Adebayo Ayelaagbe ati Iwure Nile Yoruba

No comments :

Gbajugbaja onkowe imo eko ede Yoruba ni Omowe Adebayo Ayelaagbe o si tun je oluko ede Yoruba ni awon ile-eko nile Yoruba; fun apere, St. Andrew's College of Education, Oyo. A bi i ni ilu Oyo ni nkan bii odun 1942, ibe lo ti ka ile-iwe alakoobere ati sekondiri ki o to lo keko gboye imo ninu ede Yoruba ni Yunifasiti ti Ibadan. Oun lo ko iwe "Iwure: Ijinle Adua Enu Awon Yoruba" ti o da le orisirisi ilana ti Yoruba gbe n se iwure yala nibi ayeye tabi nibi ijokoo agba.

IWURE NIBI OGUN JIJE
Ohun ti a pejo lati se lonii,
Olodumare, Oba onibu-ore,
Ma jee ko hun wa o.
..>>Ka Ekunrere Itan Yii>>>


No comments :

Post a Comment